
BBC News Yorùbá
56.6K subscribers
Verified ChannelAbout BBC News Yorùbá
Ẹ káàbọ̀ sí ìkànní WhatsApp BBC News Yorùbá. Ẹ lọ wo bí a ṣe ń dáàbò bo àwọn akọọlẹ̀ ara yín níbi https://www.bbc.com/yoruba/articles/c05l4m8nv38o
Similar Channels
Swipe to see more
Posts

Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn náà rèé: https://www.bbc.com/yoruba/articles/c1dezeyvrg1o?at_campaign=ws_whatsapp

BBC Yoruba dé ìlú Omu Aran ní ìpínlẹ̀ Kwara láti báwọn ṣe ọdún Orúgbó ti ọdún yìí, tí a sì gbọ́ ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìtàn nípa ìgbé ayé ìyá àgbà Orugbo. https://www.bbc.com/yoruba/articles/cyvmgv2j8q5o?at_campaign=ws_whatsapp

Ó ti fojú hàn báyìí pé ìwà àjẹbánu ń wáyé ní ẹ̀ka epo rọ̀bì bí ilé ẹjọ́ kan ní Ikeja ṣe sọ ọmọ alága tẹ́lẹ̀ fẹ́gbẹ́ PDP sí ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́rìnlá lórí ẹ̀sùn kíkó N2.2b jẹ. Bí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ṣe wáyé rèé áti bí àṣírí ṣe tú: https://www.bbc.com/yoruba/articles/c04evqrk7ggo?at_campaign=ws_whatsapp

Níbáyìí tó ti pé ọdún mẹ́fà tí gómìnà Seyi Makinde ti wà lórí àléèfà ní ìpínlẹ̀ Oyo, BBC Yorùbá ṣe àkójọpọ̀ kókó ohun márùn-ún ohun ti Makinde ṣe, tí ayé ṣe ń fẹ́ ẹ áti èyí tó mú kí wọn korò ojú sí i: https://www.bbc.com/yoruba/articles/ckg7m3gky4jo?at_campaign=ws_whatsapp

Ọ̀jọ̀gbọ́n kan ní fásitì, Gbade Ojo ti ṣe àgbéyẹ̀wò ìjọba ààrẹ Bola Tinubu láti ọdún méjì sẹ́yìn ní ẹ̀ka ètò ààbò, ọrọ̀ ajé, ètò ẹ̀kọ́ àti ìbáṣepọ̀ ilẹ̀ Nàíjíríà sí tilẹ̀ òkèèrè. Àlàyé rèé lórí máàkì tó fún Tinubu ní ẹ̀ka kọ̀ọ̀kan: https://www.bbc.com/yoruba/articles/c4grv6r7n6po?at_campaign=ws_whatsapp

Ọ̀rọ̀ yìí ló ti di ariwo lórí ayélujára bí ìgbẹ́jọ́ ìṣẹ̀lẹ̀ náà ṣe ń wáyé, BBC sì ṣe àlàyé ìròyìn nípa àṣírí tó ń tú nílé ẹjọ́, àbọ̀ rèé: https://www.bbc.com/yoruba/articles/cj091y90z9do?at_campaign=ws_whatsapp

BBC Yorùbá bá akẹ́kọ̀ọ́ kan tó jókòó ṣe ìdánwò WAEC nínú òkùnkùn sọ̀rọ̀, ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn rèé lórí bó ti ṣàlàyé ohun tí ojú rẹ̀ rí nípa ìdánwò náà: https://www.bbc.com/yoruba/articles/c1dezeyvrg1o?at_campaign=ws_whatsapp

Òní ló pé ọdún méjì tí ìjọba ààrẹ Bola Ahmed Tinubu gorí àlééfà, ẹ wá wo kókó mẹ́tàdínlógún nínú àwọn ọ̀rọ̀ tí ààrẹ báwọn ọmọ Nàíjíríà sọ: https://www.bbc.com/yoruba/articles/c4grv6r7n6po?at_campaign=ws_whatsapp

Àkójọpọ̀ ìròyìn rèé nípa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó wáyé nílé ẹjọ́ níbi ìgbẹ́jọ́ Nnamdi Kanu, bí òṣìṣẹ́ DSS ṣe sọ̀rọ̀, tí òkò ọ̀rọ̀ sì ń bọ́ lẹ́nu àwọn agbẹjọ́rò rẹ̀: https://www.bbc.com/yoruba/articles/ckg4l52228mo?at_campaign=ws_whatsapp

Ǹ jẹ́ o mọ̀ pé akọni òǹkọ̀wé nílẹ̀ Áfíríkà, Ngũgĩ wa Thiong'o, ṣẹ̀wọ̀n, tí wọn sì tún fi ipá bá ìyàwó rẹ̀ lò pọ̀? Ṣé o mọ ìdí tí òǹkọ̀wé náà fi kọ ìwé rẹ̀ tó gbajúmọ̀ jùlọ, ‘Weep Not Child'? Ẹ ka ìròyìn láti rí àwọn kókó ohun tó yẹ kí ẹ mọ̀ nípa Ngũgĩ wa Thiong'o, àgbà òǹkọ̀wé ilẹ̀ Africa tó jáde láyé: https://www.bbc.com/yoruba/articles/cdj98n9x7jro?at_campaign=ws_whatsapp