BBC News Yorùbá

BBC News Yorùbá

56.6K subscribers

Verified Channel
BBC News Yorùbá
BBC News Yorùbá
June 11, 2025 at 06:06 PM
Láti bí ọjọ́ díẹ̀ sẹ́yìn ni Oke Iya Mopo ti n sán lulẹ̀, èyí tó mú kí àwọn aráàlú sá fi ilé wọn sílẹ̀. Òkè Iya Mọpo ni ìtàn sọ pé ó gba Aláàfin Sango sílẹ̀ lọ́wọ́ ogun. https://www.bbc.com/yoruba/articles/c1kvdnkk8rro?at_campaign=ws_whatsapp

Comments