
Lobinco's Blog
February 2, 2025 at 12:54 PM
Ọlọ́run kì í ṣe nǹkan, kó má fi àyè ọpẹ́ sí i; tó bá pá baba lórí, a sì fi irùngbọ̀n rọ́po.
God never does a thing without leaving room for thanksgiving; if God makes a man bald, He'll give him beard in replacement.
[Those who can be thoughtful will be thankful.]