
Lobinco's Blog
February 8, 2025 at 12:46 PM
O jó n'Ífọ́n, Ifọ́n tú; o jó l'Èjìgbò, Èjìgbò fà ya bí aṣọ; o wá dé Ọ̀ràngún o tún ńjùdí; ṣé gbogbo ìlú lo fẹ́ bàjẹ́ ni?
Your dance desolated Ifon and shredded Ejigbo like clothes; yet at Orangun you were twerking your hips; must you destroy all towns?
[Avoid notoriety]