BBC News Yorùbá

BBC News Yorùbá

56.6K subscribers

Verified Channel
BBC News Yorùbá
BBC News Yorùbá
May 30, 2025 at 08:13 PM
*Àkójọpọ̀ ìròyìn wa gbogbo fún òní rèé, ẹ gbé e yẹ̀wò:* Kàyééfì ńlá, Orúgbó, ìyá àgbà tó dá ìlú Omu-Aran sílẹ̀ lẹ́ẹ̀dẹ́gbẹrin sí ẹgbẹ̀rin ọdún sẹ́yìn ‘ṣì wà láyé di òní’. https://www.bbc.com/yoruba/articles/cyvmgv2j8q5o?at_campaign=ws_whatsapp Yàtọ̀ sí àwọn tó ti kú, ọ̀pọ̀ èèyàn ni wọ́n ṣì n wá látàrí ìjàmbá yìí, gẹ́gẹ́ bí àjọ tó ń rí sí ìṣẹ̀lẹ̀ pàjáwìrì ní ìpínlẹ̀ Niger ṣe sọ. https://www.bbc.com/yoruba/articles/c1mg7lepg7yo?at_campaign=ws_whatsapp Gbajúmọ̀ òṣèré tíátà, Regina Chukwu, ni orúkọ rẹ̀ gba orí ayélujára lónìí torí ìfọ̀rọ̀wérọ̀ kan tó ṣe nípa ìgbéyàwó rẹ̀, àkójọpọ̀ ìròyìn náà rèé: https://www.bbc.com/yoruba/articles/crr7nljv9nno?at_campaign=ws_whatsapp WAEC tọrọ àforíjìn lórí báwọn akẹ́kọ̀ọ́ ṣe kọ ìdánwò nínú òkùnkùn, ilé aṣojú-ṣòfin ké sí WAEC láti sọ tẹnu rẹ̀. https://www.bbc.com/yoruba/articles/c1dezeyvrg1o?at_campaign=ws_whatsapp Níbáyìí tó ti pé ọdún mẹ́fà tí gómìnà Seyi Makinde ti wà lórí àléèfà ní ìpínlẹ̀ Oyo, èyí làwọn ohun márùn-ún ti Makinde ṣe, tí ayé ṣe ń fẹ́ ẹ áti èyí tó mú kí wọn korò ojú sí i: https://www.bbc.com/yoruba/articles/ckg7m3gky4jo?at_campaign=ws_whatsapp Ǹ jẹ́ o mọ̀ pé akọni òǹkọ̀wé nílẹ̀ Áfíríkà, Ngũgĩ wa Thiong'o, lọ sí ẹ̀wọ̀n, tí wọn sì tún fi ipá bá ìyàwó rẹ̀ sùn? https://www.bbc.com/yoruba/articles/cdj98n9x7jro?at_campaign=ws_whatsapp Iléeṣẹ́ ológun Nàìjíríà sọ pé, àwọn iléeṣẹ́ aṣèrànwọ́ kan pẹ̀lú Ọbalayé ń ṣe agbódegbà fáwọn agbésùnmọ̀mí ní Nàìjíríà. https://www.bbc.com/yoruba/articles/cgle899k9zyo?at_campaign=ws_whatsapp Ẹ wá wo ìdí tí ọgbọ̀nọjọ́ oṣù karùn ún, fi ṣe pàtàkì nínú ìtàn Nàíjíríà. https://www.bbc.com/yoruba/articles/cgj8n3depejo?at_campaign=ws_whatsapp Ọ̀jọ̀gbọ́n kan ní fásitì, Gbade Ojo ti ṣe àgbéyẹ̀wò ìjọba ààrẹ Bola Tinubu láti ọdún méjì sẹ́yìn ní ẹ̀ka ètò ààbò, ọrọ̀ ajé, ètò ẹ̀kọ́ àti ìbáṣepọ̀ ilẹ̀ Nàíjíríà sí tilẹ̀ òkèèrè. http://bbc.com/yoruba/articles/c4grv6r7n6po?at_campaign=ws_whatsapp
🙏 🇳🇬 👍 😢 5

Comments