
BBC News Yorùbá
June 1, 2025 at 08:49 AM
Lóòótọ́ ni àwọn onímọ̀ nípa ètò ìlera sọ pé, jíjẹ èso dára púpọ̀ fún ìlera. Ṣùgbọ́n, ǹjẹ́ o mọ̀ pé, àwọn èso kan tún lé ṣe àkóbá fún ara rẹ?
BBC ṣe àkójọpọ̀ èso márùn-ún tó lè ṣàkóbá fún àgọ́ ara tàbí fa ikú òjijì, wá wo àwọn èso náà.
https://www.bbc.com/yoruba/articles/cm2kv1p7d0zo?at_campaign=ws_whatsapp
❤
❤️
🇳🇬
🙏
4