BBC News Yorùbá
June 1, 2025 at 06:57 PM
A kú ìsinmi òní o! Èyí ni àkójọpọ̀ àwọn ìròyìn tí BBC Yoruba gbé jade lónìí fún ìgbádùn yín.
Bàbá yìnbọn pa ọmọ rẹ̀ lẹ́yìn tó rò pé ọ̀bọ ni òun rí nínú oko l'Ekiti
https://www.bbc.com/yoruba/articles/cvgvj7k07glo?at_campaign=ws_whatsapp
Ìtàn ayé Baṣọ̀run Gáà, ìjòyè tó yan ọba mẹ́rin, tó sì pa ọba mẹ́rẹ̀ẹ̀rin àmọ́ ọba karùn-ún ló pa á
https://www.bbc.com/yoruba/articles/cvg75djv0leo?at_campaign=ws_whatsapp
Wo àwọn èso tó lè ṣàkóbá fún àgọ́ ara tàbí fa ikú òjijì
https://www.bbc.com/yoruba/articles/cm2kv1p7d0zo?at_campaign=ws_whatsapp
Ìjàmbá ọkọ̀ pa eléré ìdárayá bí ogún lẹ́yìn tí wọ́n kúrò ní Gateway Games 2025
https://www.bbc.com/yoruba/articles/c4g62pjd5y1o?at_campaign=ws_whatsapp
Nǹkan márùn-ún tó ṣe é ṣe kí o má mọ̀ nípa Hajj
https://www.bbc.com/yoruba/articles/cpw70rywjg7o?at_campaign=ws_whatsapp
Nǹkan mẹ́jọ tó le mú kí obìnrin má rì í nǹkan oṣù láì lóyún
https://www.bbc.com/yoruba/articles/crr7x9e0jl9o?at_campaign=ws_whatsapp
Ka nípa ''Baby Mechanic'' ọ̀dọ́mọdébìnrin tó fí gbọ̀ọ̀rọ́ jẹkà nidi iṣẹ́ mọ́káliíkì
https://www.bbc.com/yoruba/media-61985137?at_campaign=ws_whatsapp
Awuyewuye lórí àwọn èèyàn tí Tinubu ń yàn sípò
https://www.bbc.com/yoruba/articles/cj42z9r4ev2o?at_campaign=ws_whatsapp
😂
😢
❤️
👍
😮
7