
BBC News Yorùbá
June 2, 2025 at 06:13 PM
Wo àwọn ìròyìn pàtàkì tó jáde lójú òpó BBC Yorùbá lónìí:
'Inú yàrá ni mo tẹ́ ọmọ oṣù méjì mi sí àmọ́ inú kàǹga la ti rí òkú rẹ̀ lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́ta'
https://www.bbc.com/yoruba/articles/c861yd05833o
'Pẹ̀lú ìbùsùn ní omí gbé ọ̀pọ̀ èèyàn lọ, kódà ọmọ ìyá kan nàá mẹ́rin wà lára wọn'
https://www.bbc.com/yoruba/articles/c93lwexz65yo
Ojú mi ni omi ṣe wọ́ ìyàwó àti ọmọ mi lọ, èèyàn mẹ́sàn-án ni èmi nìkan pàdánù nínú ẹ̀kún omi Mokwa'
https://www.bbc.com/yoruba/articles/c4gk07xpll7o
Ọ̀gá ilé-ẹ̀kọ́ di èèrò iléèwòsàn lẹ́yìn tó mú akẹ́kọ̀ọ́ tó n jìwèé wò nínú ìdánwò WAEC l'Akure
https://www.bbc.com/yoruba/articles/c5ye5rjzd8no
Iléeṣẹ́ ológun ṣèèṣì ju àdó olóró sáwọn aráàlú, àjọ ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn ní kí ìjọba ṣe ìwádìí
https://www.bbc.com/yoruba/articles/c62v6p426pgo
Ọkunrin ọmọ India tó kó ejò olóró mẹ́tàdínláàdọ́ta wọ ìlú kó sí gbaga àjọ aṣọ́bodè
https://www.bbc.com/yoruba/articles/cdxvgd7g3d1o
😢
🇳🇬
👍
4