
BBC News Yorùbá
June 3, 2025 at 05:56 AM
Ohun tó n dun ni ló n pọ̀ lọ́là ẹni. Fún àwọn obìnrin kan, tí ọkùnrin bá ṣáà ti níṣẹ́ lọ́wọ́, tó sì le tọ́jú wọn, àbùṣe bùṣe.
Ṣùgbọ́n fún àwọn obìnrin ẹ̀yà yìí, kẹ́kẹ́ nìkan ló le sọ bóyá wọn yòó gbà láti fẹ́ ọkùnrin. Ẹ wo ìdí abájọ 👇👇
https://www.bbc.com/yoruba/articles/c3rpze1yqzeo?at_campaign=ws_whatsapp
😂
🤣
4