BBC News Yorùbá

BBC News Yorùbá

56.6K subscribers

Verified Channel
BBC News Yorùbá
BBC News Yorùbá
June 3, 2025 at 06:46 PM
Wo àwọn ìròyìn pàtàkì tó wà ní ojú òpó BBC Yorùbá lónìí 'Omijé ni mo fi n wẹ ibùsùn mi lálaalẹ́ láti ìgbà tí ìgbéyàwó mi ti túká' https://www.bbc.com/yoruba/articles/c780rm8evgmo Èèyàn tó ti pàdánù ẹ̀mí wọn níbi ẹ̀kún omi Niger ti di 230, 400 di àwátì https://www.bbc.com/yoruba/articles/c17rv9nkzn7o Ta ló lẹ́tọ̀ọ́ láti pa ẹran Ileya? https://www.bbc.com/yoruba/articles/cx2e9ez79jxo 'Àwọn èèyàn ma n sá, wọ́n sì má n bẹ̀rù ẹbí mi nítorí Trichoepithelioma tó mú wa' https://www.bbc.com/yoruba/articles/c1w34dqqe3yo Ó kéré tán, aláboyún kan ló n kú láàrin ìṣẹ́jú méjé síra wọ́n lásìkò ìbímọ̀ ní Naijiria https://www.bbc.com/yoruba/articles/cn0gwjwwlgko Afurasí ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn pàdé ikú òjijì lẹ́yìn eégún l'Osogbo https://www.bbc.com/yoruba/articles/c4g6467w59ro Wo ìlú tó ti jẹ dandan fún ọkọ láti rà kẹ̀kẹ́ fún ìyàwó kí ìgbeyàwó tó ó le wáyé https://www.bbc.com/yoruba/articles/c3rpze1yqzeo Ìdí tí àkọọ́lẹ̀ 'writing' àwọn dókítà ò fi kí n dùn ún wò tí kìí sí yé èèyàn https://www.bbc.com/yoruba/articles/cy90grq52x4o?at_campaign=ws_whatsapp
❤️ 🇳🇬 🙏 3

Comments