BBC News Yorùbá

BBC News Yorùbá

56.6K subscribers

Verified Channel
BBC News Yorùbá
BBC News Yorùbá
June 4, 2025 at 07:58 AM
Láti bí ọdún mẹ́ta ni ìpèníjà ètò ààbò nípìnlẹ̀ Ondo ti n gogò sí i, pàápàá ní ìlú Owo níbi tí àwọn agbébọn ti kọlu ilé ìjọsìn kan, tí wọ́n sì pa ọ̀pọ̀ èèyàn. BBC bá kọmíṣánnà ọlọ́pàá nípìnlẹ̀ nàá, Wilfred Olutokunbo Afolabi, sọ̀rọ̀ lórí àwọn aṣeyọrí wọ́n, iye ajínigbé tí ọwọ́ ti tẹ̀, àti ibi tí nnkan dé dúró. https://www.bbc.com/yoruba/articles/c9wgq4lv5dko?at_campaign=ws_whatsapp
❤️ 😂 😢 😮 🙏 🥱 7

Comments