BBC News Yorùbá

BBC News Yorùbá

56.6K subscribers

Verified Channel
BBC News Yorùbá
BBC News Yorùbá
June 4, 2025 at 11:59 AM
Ọba aláyé ìlú nàá sọ pé ọ̀pọ̀ èèyàn ni àwọn ṣì ń wá nítorí ọ̀pọ̀ ló sá wọ inú igbó pẹ̀lú ọgbẹ́ ìbọn àti àdá lára, táwọn míì sì ń kó sínú kàǹga láti móríbọ́ lọ́wọ́ àwọn èèyàn tó wá ṣe ìkọlù ọ̀hún. https://www.bbc.com/yoruba/articles/c20xqrwl4wdo?at_campaign=ws_whatsapp
😢 🇳🇬 💔 😮 5

Comments