BBC News Yorùbá

BBC News Yorùbá

56.6K subscribers

Verified Channel
BBC News Yorùbá
BBC News Yorùbá
June 5, 2025 at 06:18 AM
Tá a bá n sọ̀rọ̀ àwọn akọni nílẹ̀ Yorùbá, Balogun Kuku, kò ṣé fi ọwọ́ rọ́ sẹ́yìn rárá. Ó di millionaire kó tó pé ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀dógún, ó dá àdúgbò Isalẹ Ijebu sílẹ̀ n'Ibadan, ó ni ìyàwó 68. Ká sọ díẹ̀ lọ́rọ̀ Kuku, ẹ̀yin nàá ẹ lọ ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìtàn yìí ní https://www.bbc.com/yoruba/articles/ce82ldn91pno?at_campaign=ws_whatsapp
👍 🙏 3

Comments