
BBC News Yorùbá
June 10, 2025 at 07:55 PM
Ẹ kú iṣẹ́ látàárọ̀! Èyí ni àkójọpọ̀ àwọn ìròyìn tó jade ní ìkànnì BBC Yoruba lónìí:
https://www.bbc.com/yoruba/articles/c9q0rxj2199o?at_campaign=ws_whatsapp
Afurasí agbébọn ṣíná ìbọn bolẹ̀ nílé ẹ̀kọ́ girama, èèyàn mẹ́wàá kú
https://www.bbc.com/yoruba/articles/c3wdj9n21zlo?at_campaign=ws_whatsapp
Lóòtọ́ àjọ̀dún Ojúde Ọba ti parí fún ọdún yìí, àmọ́ṣá díẹ̀ lára àwọn kókó tó yẹ fún àmójútó fún ọdún ọjọ́ iwájú rèé.
https://www.bbc.com/yoruba/articles/c8d13egpzzvo?at_campaign=ws_whatsapp
Ikú Albert Omondi Ojwang ti dá wàhálà sílẹ̀ lẹ́yìn tí ọ̀gá ọlọ́pàá kan fi ẹ̀sùn kàn àn pé ó sọ̀rọ̀ àbùkù sí òun lórí ayelujára.
https://www.bbc.com/yoruba/articles/ce81kk0g2xgo?at_campaign=ws_whatsapp
Bàbá ẹni odun 68 torí fóònù kó sí kọ̀ǹga ní Ibadan
https://www.bbc.com/yoruba/articles/cd628n851vlo?at_campaign=ws_whatsapp
Esie: ibùdó ìkónkan ìṣẹ̀mbáyé sí, níbi tí àwọn ère tí wọ́n bá jí kó ti ń fúnra wọn padà wálé
https://www.bbc.com/yoruba/articles/cpqe0vd7xz1o?at_campaign=ws_whatsapp
Wọ̀nyí ni ohun tí àwọn ilẹ̀ Africa tí Trump fòfin dè láti má wọ America mọ́ ń bèèrè
https://www.bbc.com/yoruba/articles/c7v7ggg99j1o?at_campaign=ws_whatsapp
Àbọ̀ ìwádìí UN rèé lórí ìdì tí àwón èèyàn kò ṣe fẹ́ ẹ́ bí ọmọ púpọ̀ mọ́ ní Naijiria
https://www.bbc.com/yoruba/articles/cwynzwlen8wo?at_campaign=ws_whatsapp
👍
❤️
🙏
🤜
🥹
6