BBC News Yorùbá
June 11, 2025 at 11:53 AM
Láìpẹ́ yìí ni òkíkí kàn nípa ìṣúná CBEX tó sọ ọ̀pọ̀ èèyàn sínú ìdàmú, ṣùgbọ́n wọ́n ní wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ padà.
https://www.bbc.com/yoruba/articles/c20q904xq50o?at_campaign=ws_whatsapp
👍
😂
2