Find WhatsApp Channels
Discover the best WhatsApp channels for news, entertainment, education and more. Our powerful search helps you find exactly what you're looking for.
Channels & Posts for #iyawo
Posts
Èyí ni bí àwọn Larubawa ṣe kọlu Mecca, tí wọ́n sì jí Òkúta Dúdú lọ - BBC News Yorùbá
A kú ìsinmi òpin ọ̀sẹ̀. Àkójọpọ̀ àwọn ìròyìn tó jade lórí BBC Yoruba ní lónìí rèé: Èyí ni bí àwọn L...
Taa ni Balogun Kuku, bàbá olówó tó mú ẹ̀sìn Islam wọ ilẹ̀ Ijebu, tó tún bẹ̀rẹ̀ ọdún Ojude Ọba? - BBC News Yorùbá
Òdú ni ẹbí Balogun Kuku nílẹ̀ Ijẹbu, tó sì jẹ́ orúkọ tí ẹnikẹ́ni kò le gbàgbé láíláí. Olówó tabua, t...
Islam, Sheik Taofeeq Akewugbagold: Ọgbà wèrè àti ilé aṣẹ́wó nilé ẹni tí kò lówó tó tún fẹ́ ìyàwó mẹ́rin - BBC News Yorùbá
Kí ni Islam sọ nípa fífẹ́ ìyàwó méjì, mẹ́ta, mẹ́rin? Ẹ wá gbọ́ ọ̀rọ̀ lẹ́nu Sheik Taofeeq Akewugbagol...
Balogun Kuku: Akọni to mú Islam wọ ilẹ̀ Ijebu, bẹ̀rẹ̀ ọdún ojúde ọba, aya 65 tó ní kò jẹ́ kó gba ẹ̀sìn Kristẹni - BBC News Yorùbá
Tá a bá n sọ̀rọ̀ àwọn akọni nílẹ̀ Yorùbá, Balogun Kuku, kò ṣé fi ọwọ́ rọ́ sẹ́yìn rárá. Ó di millio...
Biola Adebayo - Omijé ni mo fi n wẹ ibùsùn mi lálaalẹ́ láti ìgbà tí ìgbéyàwó mi ti túká - BBC News Yorùbá
Wo àwọn ìròyìn pàtàkì tó wà ní ojú òpó BBC Yorùbá lónìí 'Omijé ni mo fi n wẹ ibùsùn mi lálaalẹ́ lát...
'Inú yàrá ni mo tẹ́ ọmọ oṣù méjì mi sí àmọ́ inú kàǹga la ti rí òkú rẹ̀ lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́ta' - BBC News Yorùbá
Wo àwọn ìròyìn pàtàkì tó jáde lójú òpó BBC Yorùbá lónìí: 'Inú yàrá ni mo tẹ́ ọmọ oṣù méjì mi sí àmọ...
Ojú mi ni omi ṣe wọ́ ìyàwó àti ọmọ mi lọ, èèyàn mẹ́sàn-án ni èmi nìkan pàdánù nínú ẹ̀kún omi Mokwa' - BBC News Yorùbá
Ọmọ kan ṣoṣo ni arakúnrin Adamu ṣẹ̀ṣẹ̀ bìí, ọmọ nàá àti ìyàwò rẹ̀ sì ni àgbàrá ojò wọ́ lọ lọ́jọ́ kej...
Ìtàn ayé Orúgbó, ìyá àgbà tó dá ìlú Omu-Aran sílẹ̀ ní 13th Century àmọ̀ tí wọn ‘ló wa láyé di òní’ - BBC News Yorùbá
*Àkójọpọ̀ ìròyìn wa gbogbo fún òní rèé, ẹ gbé e yẹ̀wò:* Kàyééfì ńlá, Orúgbó, ìyá àgbà tó dá ìlú Omu...
Wo kókó ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa Ngũgĩ wa Thiong'o, àgbà òǹkọ̀wé ilẹ̀ Africa tó jáde láyé - BBC News Yorùbá
Ǹ jẹ́ o mọ̀ pé akọni òǹkọ̀wé nílẹ̀ Áfíríkà, Ngũgĩ wa Thiong'o, ṣẹ̀wọ̀n, tí wọn sì tún fi ipá bá ìyàw...
Rendez-vous à la Grande salle du Palais des Congrè...
Rendez-vous à la Grande salle du Palais des Congrès de Kara pour un débat public, organisé par IYAWO...
*Mukadzi Wechikwambo🐍🐍* https://whatsapp.com/ch...
*Mukadzi Wechikwambo🐍🐍* https://whatsapp.com/channel/0029VaxwRopBVJl3uAJzTY3m *GOTO CHANGAMIRE�...
*Mukadzi Wechikwambo🐍🐍* https://whatsapp.com/ch...
*Mukadzi Wechikwambo🐍🐍* https://whatsapp.com/channel/0029VaxwRopBVJl3uAJzTY3m *GOTO CHANGAMIRE�...